2 Samuel 20:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Adoramu ni olórí àwọn tí wọ́n ń kó àwọn eniyan ṣiṣẹ́. Jehoṣafati ọmọ Ahiludi ni olùtọ́jú àwọn àkọsílẹ̀ ní ààfin ọba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Adoramu si jẹ olori awọn agbowodè: Jehoṣafati ọmọ Ahiludi si jẹ akọwe nkan ti o ṣe ni ilu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ádórámù sì jẹ́ olórí àwọn agbowó òde: Jéhóṣáfátì ọmọ Áhílúdì sì jẹ́ olùkọsílẹ̀ ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní ìlú.