2 Samuel 20:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ira, ará ìlú Jairi náà jẹ́ ọ̀kan ninu àwọn alufaa Dafidi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ira pẹlu, ara Jairi ni nṣe alufa lọdọ Dafidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Írà pẹ̀lú, ará Jáírì ni ń ṣe àlùfáà lọ́dọ̀ Dáfídì.