2 Samuel 20:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, ọba sọ fún Amasa pé, “Pe gbogbo àwọn ọkunrin Juda jọ, kí o sì kó wọn wá sọ́dọ̀ mi láàrin ọjọ́ mẹta; kí ìwọ náà sì wá.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọba si wi fun Amasa pe, Pe awọn ọkunrin Juda fun mi niwọn ijọ mẹta oni, ki iwọ na ki o si wá nihinyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọba sì wí fún Ámásà pé, “Pè àwọn ọkùnrin Júdà fún mi níwọn ijọ́ mẹ́ta òní, kí ìwọ náà kí o sì wà níhìnyìí.”