2 Samuel 20:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Amasa bá lọ kó àwọn eniyan Juda jọ, ṣugbọn kò dé títí àkókò tí ọba dá fún un fi kọjá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Amasa si lọ lati pe awọn ọkunrin Juda: ṣugbọn o si duro pẹ jù akoko ti o fi fun u.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ámásà sì lọ láti pe àwọn ọkùnrin Júdà; ṣùgbọ́n ó sì dúró pẹ́ ju àkókò tí a fi fún un.