2 Samuel 20:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn ọmọ ogun Joabu, ati àwọn ẹ̀ṣọ́ ọba, ati gbogbo àwọn ọmọ ogun yòókù, tí wọ́n kù ní Jerusalẹmu bá tẹ̀lé Abiṣai láti lépa Ṣeba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọkunrin Joabu si jade tọ̀ ọ lọ, ati awọn Kereti, ati awọn Peleti, ati gbogbo awọn ọkunrin alagbara: nwọn si ti Jerusalemu jade lọ, lati lepa Ṣeba ọmọ Bikri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọkùnrin Jóábù sì jáde tọ̀ ọ́ lọ, àti àwọn Kérétì, àti àwọn Pélétì, àti gbogbo àwọn ọkùnrin alágbára: wọ́n sì ti Jérúsálẹ́mù jáde lọ, láti lépa Ṣábà ọmọ Bíkírì.