2 Samuel 21:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Láti ibẹ̀ ni ó ti kó egungun Saulu, ati ti Jonatani, ọmọ rẹ̀. Wọ́n sì kó egungun àwọn mejeeje tí wọ́n so kọ́ pẹlu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si mu egungun Saulu ati egungun Jonatani ọmọ rẹ̀ lati ibẹ na wá; nwọn si ko egungun awọn ti a ti so rọ̀ jọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì mú egungun Sọ́ọ̀lù àti egungun Jónátánì ọmọ rẹ̀ láti ibẹ̀ náà wá; wọ́n sì kó egungun àwọn tí a ti so rọ̀ jọ.