2 Samuel 21:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Òmìrán kan tí ń jẹ́ Iṣibibenobu, gbèrò láti pa Dafidi. Ọ̀kọ̀ Iṣibibenobu yìí wọ̀n tó ọọdunrun ṣekeli idẹ, ó sì so idà tuntun mọ́ ẹ̀gbẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iṣbi-benobu si jẹ ọkan ninu awọn òmirán, ẹniti òṣuwọn ọ̀kọ rẹ̀ jẹ ọdunrun ṣekeli idẹ, on si sán idà titun, o si gbero lati pa Dafidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iṣibi-bénóbù sì jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn òmìrán, ẹni tí ọ̀kọ̀ rẹ̀ wọn ọ̀dúnrún ṣékélì idẹ, ó sì sán idà tuntun, ó sì gbèrò láti pa Dáfídì.