2 Samuel 21:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Láti ìran àwọn òmìrán ìlú Gati ni àwọn mẹrẹẹrin ti wá, Dafidi ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ ni ó sì pa wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn mẹrẹrin wọnyi li a bi li òmirán ni Gati, nwọn si ti ọwọ́ Dafidi ṣubu, ati ọwọ́ awọn iranṣẹ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin wọ̀nyí ni a bí ní òmìrán ní Gátì, wọ́n sì ti ọwọ́ Dáfídì ṣubú àti ọwọ́ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀.