2 Samuel 21:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, fún wa ní meje ninu àwọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin, kí á lè so wọ́n kọ́ níwájú OLUWA ní Gibea, ní orí òkè OLUWA.” Dafidi dáhùn pé, “N óo kó wọn lé yín lọ́wọ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mu ọkunrin meje ninu awọn ọmọ rẹ̀ fun wa, awa o si so wọn rọ̀ fun Oluwa ni Gibea ti Saulu ẹniti Oluwa ti yàn. Ọba si wipe, Emi o fi wọn fun nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mú ọkùnrin méje nínú àwọn ọmọ rẹ̀ fún wá, àwa ó sì so wọ́n rọ̀ fún OLÚWA ní Gíbéà ti Ṣọ́ọ̀lù ẹni tí OLÚWA ti yàn.” Ọba sì wí pé, “Èmi ó fi wọ́n fún yín.”