bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare 2 Samuel 22:19
2 Samuel 22:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí mo wà ninu ìpọ́njú; wọ́n gbógun tì mí, ṣugbọn OLUWA dáàbò bò mí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ṣaju mi li ọjọ ipọnju mi; ṣugbọn Oluwa li alafẹhinti mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n wá láti borí mi lọ́jọ́ ìpọ́njú mi: ṣùgbọ́n OLÚWA ni aláfẹ̀hìntì mi.