2 Samuel 22:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní ti Ọlọrun yìí, pípé ni ọ̀nà rẹ̀, òtítọ́ ni ìlérí OLUWA, ó sì jẹ́ apata fun gbogbo àwọn tí wọ́n bá sápamọ́ sábẹ́ ààbò rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pipe li Ọlọrun li ọ̀na rẹ̀; ọ̀rọ Oluwa li a ti dan wò: on si ni asà fun gbogbo awọn ti o gbẹkẹle e.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ọlọ́run yìí, pípé ni ọ̀nà rẹ̀; ọ̀rọ̀ OLÚWA ni a ti dán wò. Òun sì ni aṣà fún gbogbo àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé e.