2 Samuel 22:42 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n wá ìrànlọ́wọ́ káàkiri, ṣugbọn kò sí ẹni tí ó lè gbà wọ́n; wọ́n pe OLUWA, ṣugbọn kò dá wọn lóhùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn wò, ṣugbọn kò si ẹnikan lati gbà wọn; nwọn wò Oluwa, ṣugbọn kò da wọn lohùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n wò, ṣùgbọ́n kò sí ẹnìkan láti gbà wọ́n; wọ́n wo OLÚWA, ṣùgbọ́n kò dá àwọn lóhùn.