2 Samuel 22:45 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn àjèjì ń wólẹ̀ níwájú mi, ẹsẹ̀kẹsẹ̀ tí wọ́n bá ti gbúròó mi, ni wọ́n ń mú àṣẹ mi ṣẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn alejo yio fi ẹ̀tan tẹriba fun mi: bi nwọn ba ti gbọ́ iró mi, nwọn o si gbọ́ ti emi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn àlejò wá láti tẹríba fún mi; bí wọ́n bá ti gbúròó mi, wọn á sì gbọ́ tèmi.