2 Samuel 22:50 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, n óo máa yìn ọ́ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, n óo máa kọ orin ìyìn sí orúkọ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina emi o fi ọpẹ fun ọ. Oluwa, larin awọn ajeji orilẹ-ède: emi o si kọrin si orukọ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà èmi ó fi ọpẹ́ fún ọ, OLÚWA, láàrin àwọn àjèjì orílẹ̀-èdè: èmi ó sì kọrin sí orúkọ rẹ.