2 Samuel 23:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Dafidi wà ní orí òkè kan tí wọ́n mọ odi yípo, ọ̀wọ́ àwọn ọmọ ogun Filistini kan ti gba Bẹtilẹhẹmu, wọ́n sì wà níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si wà ninu odi, ibudo awọn Filistini si wà ni Betlehemu nigbana.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì wà nínú odi, ibùdó àwọn Fílístínì sì wà ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù nígbà náà.