2 Samuel 23:39 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ati Uraya, ará Hiti. Gbogbo àwọn tí wọ́n jẹ́ akọni ọmọ ogun náà jẹ́ mẹtadinlogoji.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Uria ara Hitti: gbogbo wọn jẹ mẹtadilogoji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ùráyà ará Hítì. Gbogbo wọn jẹ́ mẹ́tadínlógójì.