2 Samuel 23:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn àwọn tí wọn kò mọ Ọlọrun dàbí igi ẹ̀gún tí a gbé sọnù, kò sí ẹni tí ó lè fi ọwọ́ lásán gbá wọn mú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn gbogbo awọn ọmọ Beliali yio dabi ẹgún ẹ̀wọn ti a ṣatì, nitoripe a kò le fi ọwọ́ kó wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n gbogbo àwọn ọmọ Bélíálì yóò dàbí ẹ̀gún ẹ̀wọ̀n tí a ṣátì, nítorí pé a kò lè fi ọwọ́ kó wọn.