2 Samuel 24:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Inú tún bí OLUWA sí àwọn ọmọ Israẹli, ó sì ti Dafidi láti kó ìyọnu bá wọn. OLUWA wí fún un pé, lọ ka àwọn ọmọ Israẹli ati ti Juda.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
IBINU Oluwa si ru si Israeli, o si tì Dafidi si wọn, pe, Lọ kà iye Israeli ati Juda.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìbínú OLÚWA sì ru sí Ísírẹ́lì, ó sì ti Dáfídì sí wọn, pé, “Lọ ka iye Ísírẹ́lì àti Júdà!”