2 Samuel 24:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n lọ sí Gileadi, ati sí Kadeṣi ní ilẹ̀ àwọn ará Hiti. Lẹ́yìn náà, wọ́n lọ sí Dani. Láti Dani, wọ́n lọ sí apá ìwọ̀ oòrùn títí dé Sidoni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si wá si Gileadi, ati si ilẹ Tatimhodṣi; nwọn si wá si Dan-jaani ati yikakiri si Sidoni,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì wá sí Gílíádì, àti sí ilé Tátímhódíṣì; wọ́n sì wá sí Dan-Jaanì àti yíkákiri sí Sídónì,