2 Samuel 3:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹkẹfa sì ni Itireamu, ọmọ Egila. Heburoni ni wọ́n ti bí àwọn ọmọ náà fún Dafidi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹkẹfa si ni Itreamu, ti Egla aya Dafidi bi fun u. Wọnyi li a bi fun Dafidi ni Hebroni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀kẹfà sì ni Ítíréámù, tí Égílà àya Dáfídì bí fún un. Wọ̀nyí ni a bí fún Dáfídì ni Hébúrónì.
Recommended Reading