2 Samuel 5:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Agbára Dafidi bẹ̀rẹ̀ sí pọ̀ sí i, nítorí pé OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun wà pẹlu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si npọ̀ si i, Oluwa Ọlọrun awọn ọmọ-ogun si wà pẹlu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì ń pọ̀ si i, OLÚWA Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun sì wà pẹ̀lú rẹ̀.