2 Samuel 5:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Dafidi ṣe gbogbo ohun tí OLUWA pa láṣẹ fún un, ó sì pa àwọn ọmọ ogun Filistini láti Geba títí dé Geseri.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si ṣe bẹ̃, gẹgẹ bi Oluwa ti paṣẹ fun u; o si kọlu awọn Filistini lati Geba titi o fi de Gaseri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì ṣe bẹ́ẹ̀, gẹ́gẹ́ bí OLÚWA ti pàṣẹ fún un; ó sì kọlu àwọn Fílístínì láti Gébà títí dé Gásérì.