2 Samuel 5:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn Dafidi jagun gba Sioni, ìlú olódi wọn. Sioni sì di ibi tí wọn ń pè ní ìlú Dafidi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Dafidi si fi agbara gbà ilu odi Sioni: eyi na ni iṣe ilu Dafidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Dáfídì fi agbára gba ìlú odì Síónì: èyí náà ni í ṣe ìlú Dáfídì.