2 Samuel 6:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mikali, ọmọbinrin Saulu, kò sì bímọ títí ó fi kú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mikali ọmọbinrin Saulu kò si bi ọmọ, titi o fi di ọjọ ikú rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Míkálì ọmọbìnrin Ṣọ́ọ̀lù kò sì bí ọmọ, títí o fi di ọjọ́ ikú rẹ̀ nítorí tí ó sọ̀rọ̀ òdì yìí sí Dáfídì.