2 Samuel 8:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, Dafidi ọba gbógun ti àwọn ará Filistia, ó ṣẹgun wọn, ó sì gba ìlú Mẹtẹgi-ama lọ́wọ́ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O SI ṣe, lẹhin eyi, Dafidi si kọlu awọn Filistini, o si tẹri wọn ba: Dafidi si gbà Metegamma lọwọ awọn Filistini.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì ṣe, lẹ́yìn èyí, Dáfídì sì kọlu àwọn Fílístínì, ó sì tẹrí wọn ba: Dáfídì sì gba Metegamímà lọ́wọ́ àwọn Fílístínì.