2 Timothy 2:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí àwa kò bá tilẹ̀ ṣe é gbẹ́kẹ̀lé, òun ṣe é gbẹ́kẹ̀lé nígbà gbogbo, nítorí òun kò lè tan ara rẹ̀ jẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi awa kò ba gbagbọ́, on duro li olõtọ: nitori on kò le sẹ́ ara rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí àwa kò bá gbàgbọ́, òun dúró ni olóòótọ́: Nítorí òun kò lè sẹ ara rẹ̀.