2 Timothy 2:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àgbẹ̀ tí ń ṣiṣẹ́ lóko ni ó kọ́ ní ẹ̀tọ́ sí ìkórè oko.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Àgbẹ ti o nṣe lãlã li o ni lati kọ́ mu ninu eso wọnni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àgbẹ̀ ti ó ń ṣe làálàá ni ó yẹ láti kọ́kọ́ mu nínú àwọn èso.