Acts 11:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí Peteru pada dé Jerusalẹmu, àwọn onigbagbọ tí ó jẹ́ Juu dá àríyànjiyàn sílẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati Peteru si gòke wá si Jerusalemu, awọn ti ikọla mba a sọ,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Pétérù sì gòkè wá sí Jerúsálémù, àwọn ti ìkọlá ń bá a wíjọ́