Acts 13:52 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ayọ̀ kún ọkàn àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu. Bẹ́ẹ̀ ni Ẹ̀mí Mímọ́ sì kún inú wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ-ẹhin si kún fun ayọ̀ ati fun Ẹmí Mimọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn si kún fún ayọ̀ àti fún Ẹ̀mí Mímọ́.