Acts 14:27 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n dé ibẹ̀, wọ́n pe gbogbo ìjọ jọ, wọ́n ròyìn ohun gbogbo tí Ọlọrun tọwọ́ wọn ṣe ati bí Ọlọrun ti ṣínà fún àwọn tí kì í ṣe Juu láti gbàgbọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati nwọn si de, ti nwọn si pè ijọ jọ, nwọn ròhin gbogbo ohun ti Ọlọrun fi wọn ṣe, ati bi o ti ṣí ilẹkun igbagbọ́ fun awọn Keferi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí wọ́n sì dé, tí wọ́n sì pé ìjọ jọ, wọ́n ròhìn gbogbo ohun tí Ọlọ́run fi wọ́n ṣe, àti bí ó ti ṣí ilẹ̀kùn ìgbàgbọ́ fún àwọn aláìkọlà.