Acts 14:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n dúró níbẹ̀ lọ́dọ̀ àwọn onigbagbọ fún ìgbà pípẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki iṣe igba diẹ ni nwọn ba awọn ọmọ-ẹhin gbé.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níbẹ̀ ni wọ́n ń gbé pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ni ọjọ́ púpọ̀.