Acts 15:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Báyìí ni gbogbo àwọn tí kì í ṣe Juu yóo máa wá Oluwa, ati gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn tí mo ti pè láti jẹ́ tèmi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki awọn enia iyokù le mã wá Oluwa, ati gbogbo awọn Keferi lara ẹniti a npè orukọ mi,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
kí àwọn ènìyàn ìyókù lè máa wá Olúwa, àti gbogbo àwọn aláìkọlà tí a ń fi orúkọ mi pè.’ ni Olúwa wí, ta ni ó ń ṣe nǹkan wọ̀nyí