Acts 15:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n fi ìwé rán wọn, pé: “Àwa aposteli ati àwa alàgbà kí ẹ̀yin tí kì í ṣe Juu ní Antioku, Siria ati Silisia; a kí yín bí arakunrin sí arakunrin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si kọ iwe le wọn lọwọ bayi pe, Awọn aposteli, ati awọn àgbagbà, ati awọn arakunrin, kí awọn arakunrin ti o wà ni Antioku, ati ni Siria, ati ni Kilikia ninu awọn Keferi:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn sì kọ ìwé lé wọn lọ́wọ́ báyìí pé: Àwọn àpósítélì, àti àwọn alàgbà, Tí ó jẹ̀ ti aláìkọlà tí ó wà ní Áńtíókù, àti ní Síríà: àti ní Kílíkíà.