Acts 15:31 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n kà á, inú wọn dùn sí ọ̀rọ̀ ìyànjú tí ó wà ninu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati nwọn si kà a, nwọn yọ̀ fun itunu na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí wọn sì kà á, wọ́n yọ̀ fún ìtùnú náà.