Acts 15:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn aposteli ati àwọn àgbààgbà bá péjọ láti rí sí ọ̀rọ̀ yìí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn aposteli ati awọn àgbagbà pejọ lati gbìmọ ọ̀ran yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn àpósítélì àti àwọn alàgbà péjọ láti rí si ọ̀ràn yìí.