Acts 17:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹsẹkẹsẹ ni àwọn onigbagbọ bá ṣe ètò fún Paulu láti lọ sí èbúté. Ṣugbọn Sila ati Timoti dúró ní Beria.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana li awọn arakunrin rán Paulu jade lọgan lati lọ titi de okun: Ṣugbọn Sila on Timotiu duro sibẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni àwọn arákùnrin rán Pọ́ọ̀lù jáde lọ́gán láti lọ títí de òkun: ṣùgbọ́n Sílà àti Tímótíù dúró ṣíbẹ̀.