Acts 19:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn ọkunrin náà tó mejila.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iye awọn ọkunrin na gbogbo to mejila.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iye àwọn ọkùnrin náà gbogbo tó méjìlá.