Acts 2:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà inú mi dùn, mo bú sẹ́rìn-ín. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé eniyan ẹlẹ́ran-ara ni mí, sibẹ n óo gbé ìgbé-ayé mi pẹlu ìrètí;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina inu mi dùn, ahọn mi si yọ̀; pẹlupẹlu ara mi yio si simi ni ireti:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà inú mi dùn, ahọ́n mi sì yọ̀: pẹ̀lúpẹ̀lú ara mi yóò sì sinmi ní ìrètí.