Acts 20:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àtùpà pọ̀ ninu iyàrá òkè níbi tí a péjọ sí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Fitilà pipọ si wà ni yàrá oke na, nibiti a gbé pejọ si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fìtílà púpọ̀ sì wà ní iyàrá òkè náà, níbi tí a gbé péjọ sí.