Acts 21:36 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ogunlọ́gọ̀ àwọn eniyan ni wọ́n ń tẹ̀lé wọn, tí wọn ń kígbe pé, “Ẹ pa á!”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ọ̀pọ enia gbátì i, nwọn nkigbe pe, Mu u kuro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn rọ́ tẹ̀lé e, wọ́n ń kígbe pé, “Mú un kúrò!”