Acts 22:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn Oluwa sọ fún mi pé, ‘Bọ́ sọ́nà, nítorí n óo rán ọ lọ sí ọ̀nà jíjìn, sí ọ̀dọ̀ àwọn tí kì í ṣe Juu.’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wi fun mi pe, Mã lọ: nitori emi ó rán ọ si awọn Keferi lokere réré.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nígbà náà ni Olúwa wí fún mi pé, ‘Máa lọ: nítorí èmi ó rán ọ sí àwọn aláìkọlà lókèèrè réré.’ ”