Acts 23:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí ó ti sọ báyìí, bẹ́ẹ̀ ni Anania Olórí Alufaa sọ fún àwọn tí ó dúró ti Paulu pé kí wọ́n gbá a lẹ́nu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Anania olori alufa si paṣẹ fun awọn ti o duro tì i pe, ki o gbún u li ẹnu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà yìí ni Ananíyà olórí àlùfáà pàṣẹ fún àwọn tí ó dúró tí Pọ́ọ̀lù pé, kí wọn ó gbá a lẹ́nu.