Acts 24:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn ọjọ́ marun-un, Anania olórí Alufaa dé pẹlu àwọn àgbààgbà ati agbẹjọ́rò kan tí ń jẹ́ Tatulu. Wọ́n ro ẹjọ́ Paulu fún gomina.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
LẸHIN ijọ marun Anania olori alufa ni sọkalẹ lọ pẹlu awọn alàgba ati ẹnikan Tertulu agbẹjọrò ẹniti o fi Paulu sùn bãlẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn ọjọ́ márùn-ún Ananíyà olórí àlúfáà náà sọkalẹ̀ lọ pẹ̀lú àwọn alàgbà àti ẹnìkan, Tátúlù agbẹjọ́rò, ẹni tí ó sọ̀rọ̀ ẹjọ́ Pọ́ọ̀lù fún baálẹ̀.