Acts 24:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn kò lè rí ohunkohun wí tí ẹ lè rí dìmú ninu ẹjọ́ tí wọn wá ń rò mọ́ mi lẹ́sẹ̀ nisinsinyii.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni nwọn kò le ladi ohun ti nwọn fi mi sùn si nisisiyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ní wọ́n kò lè fi ìdí ẹ̀sùn múlẹ̀ níwájú rẹ, èyí tí wọn fi mí sùn sí nísinsìn yìí.