Acts 26:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ti pẹ́ tí wọ́n ti mọ̀ mí. Bí wọn bá fẹ́, wọ́n lè jẹ́rìí sí i pé ọ̀nà àwọn Farisi ni mo tẹ̀lé ninu ẹ̀sìn ìbílẹ̀ wa, ọ̀nà yìí ló sì le jù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori nwọn mọ̀ mi lati ipilẹṣẹ, bi nwọn ba fẹ́ jẹri pe, gẹgẹ bi ẹya ìsin wa ti o le julọ, Farisi li emi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí wọ́n mọ̀ mi láti ìpilẹ̀ṣẹ̀, bí wọ́n bá fẹ́ jẹ́rìí sí i, wí pé gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà ìsìn wa tí ó lè jùlọ, Farisí ni èmi.