Acts 26:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wàyí ò! Ohun tí ó mú mi dúró nílé ẹjọ́ nisinsinyii ni pé mo ní ìrètí pé ìlérí tí Ọlọrun ṣe fún àwọn baba wa yóo ṣẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati nisisiyi nitori ireti ileri ti Ọlọrun ti ṣe fun awọn baba wa ni mo ṣe duro nihin fun idajọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nísinsìn yìí nítorí ìrètí ìlérí tí Ọlọ́run tí ṣe fún àwọn baba wa ni mo ṣe dúró níhìn-ín fún ìdájọ́.