Acts 26:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìrètí yìí ni àwọn ẹ̀yà mejila tí ó wà ní orílẹ̀-èdè wa ní, tí wọ́n ṣe ń fi ìtara sin Ọlọrun tọ̀sán-tòru. Nítorí ohun tí à ń retí yìí ni àwọn Juu fi ń rojọ́ mi, Kabiyesi!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ileri eyiti awọn ẹ̀ya wa mejejila ti nfi itara sin Ọlọrun lọsan ati loru ti nwọn nreti ati ri gba. Nitori ireti yi li awọn Ju ṣe nfi mi sùn, Agrippa Ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìlérí èyí tí àwọn ẹ̀yà wa méjèèjìlá tí ń fi ìtara sin Ọlọ́run lọ́sàn-án àti lóru tí wọ́n ń retí àti rí ì gbà. Ọba, n ítorí ìrètí yìí ni àwọn Júù ṣe ń fi mi sùn.