Acts 27:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kò pẹ́ pupọ ni afẹ́fẹ́ líle kan láti erékùṣù náà bá bì lu ọkọ̀. Wọ́n ń pe afẹ́fẹ́ náà ní èyí tí ó wá láti àríwá ìlà oòrùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kò si pẹ lẹhin na ni ìji ti a npè ni Eurakuilo fẹ lù u.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kò sì pẹ́ lẹ́yìn náà ni ìjì ti a ń pè ni Éúrákúílò fẹ́ lù ú.