Acts 28:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ní, ‘Lọ sọ fún àwọn eniyan yìí pé: Ẹ óo fetí yín gbọ́, ṣugbọn kò ní ye yín; Ẹ óo wò ó títí, ṣugbọn ẹ kò ní mọ̀ ọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wipe, Tọ̀ awọn enia wọnyi lọ, ki o si wipe, Ni gbigbọ́ ẹnyin ó gbọ́, kì yio si yé nyin; ati ni riri ẹnyin ó ri, ẹnyin kì yio si woye:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Tọ àwọn ènìyàn wọ̀nyí lọ, kí ó sì wí pé, “Ní gbígbọ́ ẹ̀yin yóò gbọ́, kì yóò sì yé e yín; à ti ni rírí ẹ̀yin yóò rí, ẹ kì yóò sí òye lati mọ̀.”