Acts 3:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà, àkókò ìtura láti ọ̀dọ̀ Oluwa, yóo dé ba yín; Oluwa yóo wá rán Mesaya tí ó ti yàn tẹ́lẹ̀ si yín, èyí nnì ni Jesu,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ki o ba le rán Kristi, ti a ti yàn fun nyin, aní Jesu;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àti kí ó baà lè rán Kírísítì tí a ti yàn fún yín tẹlẹ̀: àní Jésù.